eko elewe kan awo ekun die ao la eko yen larin tewetewe ao fi awo ekun si larin ao jo pelu odindi atare kan ao wa da sinu oti shinap ao ma mu die die , aba wa lara mu
Opolo ijokun aye kan ao fi ewe lapa funfun 8 tele ikoko agbe opolo lee pelu atare odidi kan ao da ewe lapa funfun 8 minran bo ao jo.. Ao lo kuna ninu ikoko naa ao fi fo eko mun ninu isasun naa ao walo fo ikoko naa mole lorita meta lobatan lona basi fun e..