Skip to main content

EYONU ASINA FUN GBOGBO ENI TONA BADI MON

Opolo ijokun aye kan ao fi ewe lapa funfun 8 tele ikoko agbe opolo lee pelu atare odidi kan ao da ewe lapa funfun 8 minran bo ao jo..
Ao lo kuna ninu ikoko naa ao fi fo eko mun ninu isasun naa ao walo fo ikoko naa mole lorita meta lobatan lona basi fun e..

Comments

Popular posts from this blog

ATUDE ATI ITUWO AWON AGBA

ATUDE/ITUWO AWON AGBA. Eso werenjeje lopolopo,ata ijosin egbo tude...ao lo kuna,ninu od,ao fi ose dudu ko sinu ikarahun igbin.Ao ma buwe ni ale patapata. ITUWO AWON AGBA TO DAJU. Enu opiye,oju ologbo(eso werenjeje),epo obo,ewe ajeobale ao gun lodo,ose dudu,ao ma buwe ni ale tabi idaji kutu.

ASINA OWO TAARA

Aowa Opolo Gbigbe 3 Eku Asin Gbigbe 3 Oga gbigbe 3 Ewe Afeloru Eso were njeje pupo Isun ogiri Sako aoge si 16 Atare nla 3 Esinsin (house fly) eyo 9 Igbin apinnu nla kan Aojo papo aowa lo daadaa ao kosi sinu igo funfun ni. Aowa gbe sinu aso funfun kan aowa gbe pamo fun Ojo meta . Lehin Ojo keta aowa lobe Sara re lodo awon onifa tabi awon Oni yepe . Ti abati se Sara re . Ise bere niyen........ Lilo re. Epo pupa lalale Eko Tutu tabi hot 45% eyikeyi aoma mu lararo kutukutu......