Skip to main content

ATUDE ATI ITUWO AWON AGBA

ATUDE/ITUWO AWON AGBA.
Eso werenjeje lopolopo,ata ijosin egbo tude...ao lo kuna,ninu od,ao fi ose dudu ko sinu ikarahun igbin.Ao ma buwe ni ale patapata.

ITUWO AWON AGBA TO DAJU.
Enu opiye,oju ologbo(eso werenjeje),epo obo,ewe ajeobale ao gun lodo,ose dudu,ao ma buwe ni ale tabi idaji kutu.

Comments

Unknown said…
Thanks so much sir
Unknown said…
Ejowo kini itumon ao gun ninu Od
Unknown said…
Thanks so much sir ❤️
Unknown said…
A dupe pupo alekun imo ati oye l'ase edumare 🙏🏻🙏🏻🙏🏻
AY said…
Ewe a maa je o.Adupe gidi
Taiwo said…
Adupe pupo lowo yin ewe ama je fun yin o

Popular posts from this blog

ASINA OWO TAARA

Aowa Opolo Gbigbe 3 Eku Asin Gbigbe 3 Oga gbigbe 3 Ewe Afeloru Eso were njeje pupo Isun ogiri Sako aoge si 16 Atare nla 3 Esinsin (house fly) eyo 9 Igbin apinnu nla kan Aojo papo aowa lo daadaa ao kosi sinu igo funfun ni. Aowa gbe sinu aso funfun kan aowa gbe pamo fun Ojo meta . Lehin Ojo keta aowa lobe Sara re lodo awon onifa tabi awon Oni yepe . Ti abati se Sara re . Ise bere niyen........ Lilo re. Epo pupa lalale Eko Tutu tabi hot 45% eyikeyi aoma mu lararo kutukutu......