Skip to main content

Posts

Showing posts from December 24, 2017

ATUDE ATI ITUWO AWON AGBA

ATUDE/ITUWO AWON AGBA. Eso werenjeje lopolopo,ata ijosin egbo tude...ao lo kuna,ninu od,ao fi ose dudu ko sinu ikarahun igbin.Ao ma buwe ni ale patapata. ITUWO AWON AGBA TO DAJU. Enu opiye,oju ologbo(eso werenjeje),epo obo,ewe ajeobale ao gun lodo,ose dudu,ao ma buwe ni ale tabi idaji kutu.

AWON EYONU

EYONU AWON AYE. Ori ejo oka tolase lenu kan, Egbo owu akese,ewe omisinmisin gogoro,ewe omisinmisin pelebe,egbo akerejipon,eyele funfun kan,odidi atare kan,ao jopo ao ma fila oyin ojuda laro lale diedie. EYONU AWON AYE. Epo obo lopolopo,Adaripon meta,eyin ororo meta,ewe egele lopolopo odidi atare meta,jijo po,ao ma filo eko tutu loru ganjo. EYONU AWON AYE. Ereele ewe ajeobale lopolopo,eso laa pupa,owo aganran(tuntun)marun otooto ,iye kanakana,oromo adie kan,odidi atare gidi kan,jijo ,eko tutu tabi milk alagolo kan tabi oyin ni lilo re ni idaji kutu diedie. OSO EYONU AWON AGBA. Ori oka tolase lenu meje,odidi eye elulu meje,odidi atare gidi meje,awo lili totobi tope dada meje,ipe oore 33,ao jo,lilo kuna sibikan,ao ma fi ogere epo pupa lo diedie ...odaju ..pupo contracts ti ao mo nipa re yio ma wole ju.Gbogbo ohun ti abatin dawole bayi yio ma yori si rere ni. EYONU ASINA TO DAJU GIDI. Ifun adie to tobi dada,epo obo ,ewe olorungo,ao gun gbogbo re kuna ,ao fose dudu ko,ao ma buw...

IMO KIKUN FUN OMO ILE IWE

IMO KIKUN FUN OMO ILE IWE Egusi itoro, a o lo yoo kunna, egusi ile, a o lo yoo kunna, ata jije(7) ni a o lo si, a o wa bu omi si inu abo kan, a o wa ka Iwe Eksodu ori keje (7) si omi yi, bi a ba ka tan, a o daasi inu isasun, a o wa ko awon nkan ti a lo yi si pelu, a o wa joo eyin ibile kan si, a o se yoo jinna, a o gbodo fi epo ati iyo si rara o, Adi agbon ni a o fi se epo re, nigbati o ba jinna, a o wa fi Okuta meta (3) se aro sile, orire ni a o so si titi yoo fi tutu bi o ba tutu tan, ihoho ni omo ile iwe na yoo je ni ekan soso, omo na yoo si ni Imo pupo. Asiri ni o

ASINA OWO TAARA

Aowa Opolo Gbigbe 3 Eku Asin Gbigbe 3 Oga gbigbe 3 Ewe Afeloru Eso were njeje pupo Isun ogiri Sako aoge si 16 Atare nla 3 Esinsin (house fly) eyo 9 Igbin apinnu nla kan Aojo papo aowa lo daadaa ao kosi sinu igo funfun ni. Aowa gbe sinu aso funfun kan aowa gbe pamo fun Ojo meta . Lehin Ojo keta aowa lobe Sara re lodo awon onifa tabi awon Oni yepe . Ti abati se Sara re . Ise bere niyen........ Lilo re. Epo pupa lalale Eko Tutu tabi hot 45% eyikeyi aoma mu lararo kutukutu......

APARUN

Eku Asin meta, Oga gbigbe meta, Opolo meta, gun lototo ti yio kunna dada, ao wa toju igo olomori kan ao ko egbo Tude si, Akogun die, egbo gbogbo se, pelu eru Alamo, ao da eyi ti a lo le lori, ao da Adin dudu le ti yio mu dada. Ao lo gbe pamo si Inu igbo fun ojo merindinlogun 16 days.. Sibi imuko meta fun agbalagba,, eyokan fun omode. IKILO. Ma se gbe ise yi sibi ti awon ogun miran ba wa o