Skip to main content

IMO KIKUN FUN OMO ILE IWE

IMO KIKUN FUN OMO ILE IWE
Egusi itoro, a o lo yoo kunna, egusi ile, a o lo yoo kunna, ata jije(7) ni a o lo si, a o wa bu omi si inu abo kan, a o wa ka Iwe Eksodu ori keje (7) si omi yi, bi a ba ka tan, a o daasi inu isasun, a o wa ko awon nkan ti a lo yi si pelu, a o wa joo eyin ibile kan si, a o se yoo jinna, a o gbodo fi epo ati iyo si rara o, Adi agbon ni a o fi se epo re, nigbati o ba jinna, a o wa fi Okuta meta (3) se aro sile, orire ni a o so si titi yoo fi tutu bi o ba tutu tan, ihoho ni omo ile iwe na yoo je ni ekan soso, omo na yoo si ni Imo pupo. Asiri ni o

Comments

Popular posts from this blog

ATUDE ATI ITUWO AWON AGBA

ATUDE/ITUWO AWON AGBA. Eso werenjeje lopolopo,ata ijosin egbo tude...ao lo kuna,ninu od,ao fi ose dudu ko sinu ikarahun igbin.Ao ma buwe ni ale patapata. ITUWO AWON AGBA TO DAJU. Enu opiye,oju ologbo(eso werenjeje),epo obo,ewe ajeobale ao gun lodo,ose dudu,ao ma buwe ni ale tabi idaji kutu.

ASINA OWO TAARA

Aowa Opolo Gbigbe 3 Eku Asin Gbigbe 3 Oga gbigbe 3 Ewe Afeloru Eso were njeje pupo Isun ogiri Sako aoge si 16 Atare nla 3 Esinsin (house fly) eyo 9 Igbin apinnu nla kan Aojo papo aowa lo daadaa ao kosi sinu igo funfun ni. Aowa gbe sinu aso funfun kan aowa gbe pamo fun Ojo meta . Lehin Ojo keta aowa lobe Sara re lodo awon onifa tabi awon Oni yepe . Ti abati se Sara re . Ise bere niyen........ Lilo re. Epo pupa lalale Eko Tutu tabi hot 45% eyikeyi aoma mu lararo kutukutu......