EYONU AWON AYE. Ori ejo oka tolase lenu kan, Egbo owu akese,ewe omisinmisin gogoro,ewe omisinmisin pelebe,egbo akerejipon,eyele funfun kan,odidi atare kan,ao jopo ao ma fila oyin ojuda laro lale diedie. EYONU AWON AYE. Epo obo lopolopo,Adaripon meta,eyin ororo meta,ewe egele lopolopo odidi atare meta,jijo po,ao ma filo eko tutu loru ganjo. EYONU AWON AYE. Ereele ewe ajeobale lopolopo,eso laa pupa,owo aganran(tuntun)marun otooto ,iye kanakana,oromo adie kan,odidi atare gidi kan,jijo ,eko tutu tabi milk alagolo kan tabi oyin ni lilo re ni idaji kutu diedie. OSO EYONU AWON AGBA. Ori oka tolase lenu meje,odidi eye elulu meje,odidi atare gidi meje,awo lili totobi tope dada meje,ipe oore 33,ao jo,lilo kuna sibikan,ao ma fi ogere epo pupa lo diedie ...odaju ..pupo contracts ti ao mo nipa re yio ma wole ju.Gbogbo ohun ti abatin dawole bayi yio ma yori si rere ni. EYONU ASINA TO DAJU GIDI. Ifun adie to tobi dada,epo obo ,ewe olorungo,ao gun gbogbo re kuna ,ao fose dudu ko,ao ma buw...